Copy
Resources
Analysis
Bookmarks
A
Font
G
rammar
Language
Help translate STEP into your language.
Feedback
FAQ
More
Download STEP
Video demonstrations
Guide & Instructions
Available Bibles etc
Classical interface
Reset everything
How to help
Feedback
Privacy policy
Copyright & licenses
About...
Search
Luke 18:29-30
29
Ó sì wí fún wọn pé,
“Lóòótọ́ ni mo wí fún yín, kò sí ẹni tí ó fi ilé, tàbí aya, tàbí ará, tàbí òbí, tàbí ọmọ sílẹ̀, nítorí ìjọba Ọlọ́run,
30
Tí kì yóò gba ìlọ́po púpọ̀ sí i ní ayé yìí, àti ní ayé tí ń bọ̀ ìyè àìnípẹ̀kun.”
Copyright information for
YorBMYO