Copy
Resources
Analysis
Bookmarks
A
Font
G
rammar
Language
Help translate STEP into your language.
Feedback
FAQ
More
Download STEP
Video demonstrations
Guide & Instructions
Available Bibles etc
Classical interface
Reset everything
How to help
Feedback
Privacy policy
Copyright & licenses
About...
Search
Matthew 20:26-27
26
Ṣùgbọ́n èyí yàtọ̀ láàrín yín. Dípò bẹ́ẹ̀, ẹni tí ó bá ń fẹ́ ṣe olórí láàrín yín, ní láti ṣe bí ìránṣẹ́ fún yín ni,
27
Àti ẹni tí ó bá fẹ́ ṣe olórí nínú yín, ẹ jẹ́ kí ó máa ṣe ọmọ ọ̀dọ̀ yin.
Copyright information for
YorBMYO