Copy
Resources
Analysis
Bookmarks
A
Font
G
rammar
Language
Help translate STEP into your language.
Feedback
FAQ
More
Download STEP
Video demonstrations
Guide & Instructions
Available Bibles etc
Classical interface
Reset everything
How to help
Feedback
Privacy policy
Copyright & licenses
About...
Search
Psalms 135:15-17
15
Fàdákà òun wúrà ni èrè àwọn aláìkọlà,
iṣẹ́ ọwọ́ ènìyàn ni.
16
Wọ́n ní ẹnu, ṣùgbọ́n wọn kò le sọ̀rọ̀;
wọ́n ní ojú, ṣùgbọ́n wọn kò fi ríran.
17
Wọ́n ní etí, ṣùgbọ́n wọn kò fi gbọ́rọ̀;
bẹ́ẹ̀ ni kò si èémí kan ní ẹnu wọn
Copyright information for
YorBMYO